Get Free and Complete Copies of my prayers books on
Ulist at https://ulist.com.ng/bookshop or
Amazon at https://amazon.com/author/thebestsellingauthorx
Subscribe to our Youtube Channel "Prayers Altar (Pepe Adura)" for more prayers videos by clicking here https://youtube.com/channel/UCgHL2jLP1_vAntGV7uS1-_A
Mo gbadura fun yin. Ninu osu tuntun yi, a dara fund yin.
Bi ibi ba n lo niwaju, e o ni ba, bi ibi ba n bo leyin, ko ni baa yin
E o ni sase ti. Oju o ni ti yin ni Oruko Jesu
Aye o ni ridi yin
Ota o ni yo yin
Oke oke le o maa lo
Gbogbo ohun te ba da owo le o ma ma yori si rere ni oruko Jesu
Awon eni ibi to n daamu gbogbo agbaye, won o ni ya odo yin
E o ni rogun ekun. E o ni rogun ose ni Oruko Jesu
Iroyin ayo ni yoo maa je tiyin
E ti goke ise rere, e o ni jabo ni oruko Jesu.
E o ni toro je. E e ni taraka
E e ni wo akisa
Iwaju Iwaju le oo maa lo ni oruko Jesu
Gbogbo ohun ti Olorun fi n ke eniyan to ayo won eni fi n dale, olorun a fi ke yin ni Oruko Jesu
E o ma lo layo, e o ma bo layo
E o ma ga si. E o ni lo le
Tile tile, tona tona, yoo maa dara fun yin
Ori yin o nii ko adura
Tiyin o ni soro se
Oba to n gbo adura a gbo adura yin
So shall it be in Jesus name we have prayed. Amen!
0 comments:
Kindly comment here!